Idaniloju Ati Ijewo Re Nipa Ihinrere{¡¡}-(Iyipada Póòlù)
MAR 24, 2024
Description Community
About
Íşe àwon àpóstélì{Acts 9:1-9}....boya o da o l'ójú pe Kristi ni messiah naa, omo Olorun sugbon şe igbe aye re l'apapo je ti idalebi ohun idarudapo?🤔....tabi o jeri gbe igbagbo re ninu Kristi?🤔....👩‍💻👨‍💻🧑‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻....


Kan si wa l'ori:
reviewseries20@gmail.com/
+447417522082
Comments