Review series Episodes

Review Ministries

About

Having a new life in Christ and taking your relationship with Him one day at a time, to the next level.....


Note: Review Ministries Gives Credit For All Music Played During Every Cast(Which Includes The Writers/Composers, Producers, etc). Thank You For The Labour Of Love.

Available on

Community

650 episodes

Ìkùnà Kìí Şe Òpin{¡}

D'arapo mo wa l'owuro yi fun isin ajinde nibiti a o ti maa s'oro ati kékòó nipa awon egbe ìsòrí eniyan meji.....Matiu 26:31-35.....Halleluyah! Jesu Oluwa Jinde!🎶🎵🎼......

24m
Mar 31, 2024
Miracle In The Disappointment {¡¡}- {The Ones Who Stayed Regardless}Luke 23:27&55

Although there was a great Scattering, some decided to take their disappointment to the foot of the cross ✝️.....join us to look at these group of people and what became of them....John 19:25-27,.....Luke 24:1-11...🧑‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👨‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻.... Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

36m
Mar 30, 2024
Idaniloju Ati Ijewo Re Nipa Ihinrere{¡¡}-(Iyipada Póòlù)

Íşe àwon àpóstélì{Acts 9:1-9}....boya o da o l'ójú pe Kristi ni messiah naa, omo Olorun sugbon şe igbe aye re l'apapo je ti idalebi ohun idarudapo?🤔....tabi o jeri gbe igbagbo re ninu Kristi?🤔....👩‍💻👨‍💻🧑‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻.... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

19m
Mar 24, 2024
The Disappointment And The Disappointed{¡}-{The Scattering} Mark 14:27

Join us as we start our Easter series looking at how the disciples' hope became shattered {or so they thought} when things took a different turn and Jesus was arrested....they were helpless and they scattered....Mark 14:43-52👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻🧑‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻...... Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

30m
Mar 23, 2024
Idanil'oju Ati Ijéwó Re Nipa Ìhìnrere{¡}-{Ijewo Igboya Balogun Orún

Işèlè ńlá kan şè si okunrin kan l'ésė agbelebu nibi ti a kan Jesu mo. Okunrin naa ni bibeli pe ni: "balogun orún".....òrò rè ni a m'énubà ni sókí ninu iwe ihinrere Marku 15:33-39.....Je ka jo kó eko ti tonii 👩‍💻🧑‍💻👨‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻...... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

20m
Mar 17, 2024
Bases Of Our Hope {v}- Hebrews 6:19

Join us to round up this wonderful series that God has used to inspire us as we gradually move towards Easter, celebrating the life, death and resurrection of Christ our HOPE....🧑‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👨‍💻🧑‍💻👩‍💻......

23m
Mar 16, 2024
Ipade Pelu Olorun {¡¡¡}-{Y'ara L'ati Gbo, L'ora L'ati F'ohun}

D'arapo mo wa bi a ti n mu èkó yii wa s'opin fun apeere to şe pataki nipa; bi a ti le e mò nigbati Olorun ba n ba wa s'òrò👩‍💻👨‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻.....

19m
Mar 10, 2024
Bases Of Our Hope {¡v}- Psalm 42:5

Today we look at a man in distress, pain or sorrow but yet, recalled the faithfulness of God from yesterday/the past and was able to draw strength from that because he knew God always comes up with his plans for us as long as we hope in him....Jeremiah 29:11-13....🧑‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻..... Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

22m
Mar 09, 2024
Ipade Pelu Olorun {¡¡}-{Iwo Ati Olorun Nikan}....Isaiah 1:18

Bawo ni o ti le e şe e şe fun wa l'oni l'ati maa pade Olorun loorekoore botilè je pe kirakita, ariwo, işe ati igbokegbodo aye po?🤔.....O şe d'arapo mo wa fun eko ti oni.....🧑‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻.... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

17m
Mar 03, 2024
Bases Of Our Hope {¡¡¡}- Romans 15:13

Today, we look at what happened in Shunem when Elisha spoke words of hope to a woman with no son.....join us to review 2kings 4:8-16....17-28.....👨‍💻🧑‍💻👩‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻🧑‍💻..... Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

23m
Mar 02, 2024
Ipade Pelu Olorun {¡}-{Iwo Ati Olorun Nikan};Orin-Dafidi 8:3&4

Okan l'ara awon ohun ti o şe pataki ti a ba fe ni ajoşepò ti o dara, dun, danmoran pelu enikeni tii ba a jé tabi ti a yan l'aayo ni riri daju pe a n ya akoko s'oto loorekoore l'ati maa pade, wa papò, s'òrò ojukoroju pelu won. Bi a ba wa n s'òrò nipa ajoşepo eniyan pelu Olorun nko/Olorun pelu eniyan....🤔.....d'arapo mo wa fun eko yi....👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻.... Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

19m
Feb 25, 2024
Bases Of Our Hope {¡¡}-1 Peter 3:15

With promises comes hope and with hope, comes faith{to wait/persevere). Today we look at how Rahab held on to the "bases of her hope" to the very end; ready to answer with explanations all sort of questions about it.👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻..... Contact us via; reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

20m
Feb 24, 2024
Agbara Ti Aşayan Ni L'ori Iwa Ati Işe Nipa Ti Ara Ati Ęmí {¡v}

D'arapo mó wa l'ati mu èkó yi wá s'opin nigbati a o ma wo igbesi aye Solomoni ni ranpe l'ati inu iwe awon oba kini, ori kokanla.....(1 Kings 11:1-10)....🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻...... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

19m
Feb 18, 2024
Bases Of Our Hope {¡}

Join us as we start another powerful series that explains the power of hope. We are laying the foundation with Isaiah 40:31 and also sharing an interesting story to drive it home a bit....study with us.....👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻..... You can reach us on: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

19m
Feb 17, 2024
Agbara Ti Aşayan Ni L'ori Ìwà Ati Işe Nipa Ti Ara Ati Èmí{¡¡¡}

Awon oba kini(1 Kings 21:25) so fun wa bi ìwà buburu, ibi ati iwa ika oba Ahabu ti wa ni ipele miiran ti o ga julo tori o yan Jesebeli ni aya...sugbon a ko k'ekòó nipa awon l'óko l'áyà yi l'oni bikoşe omiran bii ti won; Samsoni....d'arapo mo wa fun èkó ti oni👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻..... Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

22m
Feb 11, 2024
Yes Alone {v}-{Designed Just For You}

To round up this series, it is important that we look briefly at a life of a man of God who fearlessly answered his 'yes alone' doing everything the Lord required of him as we read from 1 Kings 17:1-7, 8-11&15....Chapter 19 comes on later.....study with us....👨‍💻👩‍💻🧑‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻 Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

22m
Feb 10, 2024
Agbara Ti Åşàyàn Ní L'ori Ìwà Áti Ìşe Nipa Ti Ara Ati Èmí {¡¡}

Looti yan lai ni arojinle awon ipalara ti gbigbe iha ila-oorun pelu awon ti oju Olorun koro si; le e fa fun ohun ati idile re......tesiwaju eko yi pelu wa ni Genesisi ori kokan-din-l'ogun{19}......👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻....... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082

20m
Feb 04, 2024
Yes Alone {¡v} {Designed Just For You}

Listen to today's study episode friends and learn the important lesson that: God does not stop us from making choices apart from his will or outside his will; we just must be ready to face the consequences. Think about it.....🤔🤔...👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻.......

21m
Feb 03, 2024
Agbara Ti Aşayan Ni L'ori Iwa Ati Işe Nipa Ti Ara Ati Ęmí{¡}

Kini a n pe ni àşàyan? Báwo ni ó ti le şe àkóbá fun ìwà àti ìşe bi eniti o n yan ko ba kíyèsára tabi l'arojinle? D'arapo mo wa l'ori eko onipele titun yi ka jo wa oro Olorun jinle....👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👨‍💻 Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com (+44)7417522082

19m
Jan 28, 2024
Yes Alone {¡¡¡}-{Designed Just For You}

Genesis chapters 12&13 is where we'll be reading today as we look at what was meant to be a "yes alone" but took an extra company....."a relative".....against God's instructions....join us and let's study together 👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻 Contact us via email: reviewseries20@gmail.com (+44)7417522082

19m
Jan 27, 2024
Sisin Olorun T'okan, T'ara, T'emi{¡¡}-{Wa Aaye L'ati Tóju Ara Re}

L'oni, ę ję ki awa naa ķó èkó pàtàkì ninu ohun ti Jesu fi ko awon omo ehin nipa isinmi l'ati inu iwe Marku 6.....d'arapò mó wa...👩‍💻🧑‍💻👨‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻...... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com +447417522082

15m
Jan 21, 2024
Yes Alone{¡¡}- {Designed Just For You}

Moses who earlier on complained about eloquence, standing to face Pharaoh, etc and wanted a company asides God had to stand alone to quickly bring the people back to God when Aaron decided to put the laws of God(Exodus 20:3&4) by the side, yielding to public pressure.....Exodus 32:1-6, 21-25......or read all...👨‍💻👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👩‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻.... Contact Us via email: reviewseries20@gmail.com +447417522082

19m
Jan 20, 2024
Sinsin Olorun T'okan, T'ara, T'emi{¡}{Sise Itoju Ara Re Daadaa Ati L'ona Ti O To}

D'arapo mo wa l'ati wo ohun ti Olorun pa l'ase ni sise itoju ago ara wa l'ati le sin-in pelu otito inu ati okan ti o ye kooro.....👩‍💻🧑‍💻👩‍💻🧑‍💻👩‍💻🧑‍💻👩‍💻🧑‍💻....

15m
Jan 14, 2024
Yes Alone{¡}{Designed Just For You}

Welcome again to another year where we shall continue to review the word of God to encourage, motivate and lift our spirits...why don't you start this brand new series with us,...and then continue to come back for more every weekend? Let's study the ancient word together...👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻🧑‍💻👩‍💻👨‍💻.....

25m
Jan 13, 2024
Idupe Ati Adura Fun Odun Titun

D'arapo mo wa l'ati dupe fun aşeye Odun nigbati a o maa fi odun wa titun le Olorun l'owo pelu....E je ki a gbadura 🙏🙏🙏🙏🙏.....

14m
Jan 07, 2024
New Year Thanksgiving And Prayer

Join us on review to give thanks unto the lord and praise him, also to commit the new year unto him....Amen....🎵🎶🔊🎼🥁🎻🎺💃🕺🥁🎹🎼....

15m
Jan 06, 2024
Enlę Bę o, Njé Ē L'aaye?

D'arapo mo wa ka jo wo ohun ti o şęlę si Maria ati Josefu ni akoko akobi omo won tii şe omo Olorun....ani Jesu Kristi...Bawo ni keresi akoko ti ri??🤔...🎻🎺🎷🎼🎼🎶🎵👑👑👑🎹🎵🎶🥁🥁.... Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com 07417522082(+44)

17m
Dec 24, 2023
CHRISTMAS; WHAT DO YOU SEE?👀👀👓👓

Join our friends Stephen, Leah and Noah as they they present the last topic for the year(2023); inviting mum(Esther) as their 'guest'.....It's Christmas; What do you see? What have you always seen?🤔🤔.....🌲🌲🎶🎵🎼🎹🥁🎻🎺🎷🌲🌲👑👑👑👑... Contact us via email; reviewseries20@gmail.com

23m
Dec 23, 2023
Oba Kan Gboogi Oninuure{¡¡}👑

Matiu 1:18-25...d'arapo mo wa l'ati wo oba ti a bi fun igbala araye ti o si tun pe ara re ni: "Oluso aguntan rere"...Johannu 10:11.....👑🎷🎺🎶🎵🥁🎻🎹🎼🔊💃💃👑...... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com

18m
Dec 17, 2023
The Servant Job: Dare/Daring To Be Different 🧤

What do you wanna be when you grow up?🤔...😊....why don't you join us to find out what this is all about as you start your Christmas here, celebrating the true and one kind of a king👑👑👑🎷🎺🎻🥁🎶🎵🎹🎼🔊🔊.... Contact us via email: reviewseries20@gmail.com

26m
Dec 16, 2023