

D'arapo mo wa l'owuro yi fun isin ajinde nibiti a o ti maa s'oro ati kékòó nipa awon egbe ìsòrí eniyan meji.....Matiu 26:31-35.....Halleluyah! Jesu Oluwa Jinde!🎶🎵🎼......


Although there was a great Scattering, some decided to take their disappointment to the foot of the cross ✝️.....join us to look at these group of people and what became of them....John 19:25-27,.....Luke 24:1-11...🧑💻👩💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👨💻🧑💻👩💻👨💻👩💻🧑💻.... Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Íşe àwon àpóstélì{Acts 9:1-9}....boya o da o l'ójú pe Kristi ni messiah naa, omo Olorun sugbon şe igbe aye re l'apapo je ti idalebi ohun idarudapo?🤔....tabi o jeri gbe igbagbo re ninu Kristi?🤔....👩💻👨💻🧑💻🧑💻👨💻👩💻.... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Join us as we start our Easter series looking at how the disciples' hope became shattered {or so they thought} when things took a different turn and Jesus was arrested....they were helpless and they scattered....Mark 14:43-52👨💻👩💻🧑💻👩💻👨💻🧑💻🧑💻👨💻👩💻...... Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Işèlè ńlá kan şè si okunrin kan l'ésė agbelebu nibi ti a kan Jesu mo. Okunrin naa ni bibeli pe ni: "balogun orún".....òrò rè ni a m'énubà ni sókí ninu iwe ihinrere Marku 15:33-39.....Je ka jo kó eko ti tonii 👩💻🧑💻👨💻🧑💻👨💻👩💻👨💻👩💻🧑💻...... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Join us to round up this wonderful series that God has used to inspire us as we gradually move towards Easter, celebrating the life, death and resurrection of Christ our HOPE....🧑💻👩💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👨💻🧑💻👩💻......


D'arapo mo wa bi a ti n mu èkó yii wa s'opin fun apeere to şe pataki nipa; bi a ti le e mò nigbati Olorun ba n ba wa s'òrò👩💻👨💻👨💻👩💻🧑💻🧑💻👨💻👩💻.....


Today we look at a man in distress, pain or sorrow but yet, recalled the faithfulness of God from yesterday/the past and was able to draw strength from that because he knew God always comes up with his plans for us as long as we hope in him....Jeremiah 29:11-13....🧑💻👩💻👨💻👩💻👨💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻..... Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Bawo ni o ti le e şe e şe fun wa l'oni l'ati maa pade Olorun loorekoore botilè je pe kirakita, ariwo, işe ati igbokegbodo aye po?🤔.....O şe d'arapo mo wa fun eko ti oni.....🧑💻👨💻👩💻👨💻🧑💻👩💻🧑💻👨💻👩💻.... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Today, we look at what happened in Shunem when Elisha spoke words of hope to a woman with no son.....join us to review 2kings 4:8-16....17-28.....👨💻🧑💻👩💻🧑💻👩💻👨💻👩💻👨💻🧑💻..... Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Okan l'ara awon ohun ti o şe pataki ti a ba fe ni ajoşepò ti o dara, dun, danmoran pelu enikeni tii ba a jé tabi ti a yan l'aayo ni riri daju pe a n ya akoko s'oto loorekoore l'ati maa pade, wa papò, s'òrò ojukoroju pelu won. Bi a ba wa n s'òrò nipa ajoşepo eniyan pelu Olorun nko/Olorun pelu eniyan....🤔.....d'arapo mo wa fun eko yi....👩💻👨💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻.... Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


With promises comes hope and with hope, comes faith{to wait/persevere). Today we look at how Rahab held on to the "bases of her hope" to the very end; ready to answer with explanations all sort of questions about it.👨💻👩💻🧑💻👩💻🧑💻👨💻👨💻👩💻🧑💻..... Contact us via; reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


D'arapo mó wa l'ati mu èkó yi wá s'opin nigbati a o ma wo igbesi aye Solomoni ni ranpe l'ati inu iwe awon oba kini, ori kokanla.....(1 Kings 11:1-10)....🧑💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👩💻...... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Join us as we start another powerful series that explains the power of hope. We are laying the foundation with Isaiah 40:31 and also sharing an interesting story to drive it home a bit....study with us.....👩💻🧑💻👨💻👩💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻👨💻..... You can reach us on: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Awon oba kini(1 Kings 21:25) so fun wa bi ìwà buburu, ibi ati iwa ika oba Ahabu ti wa ni ipele miiran ti o ga julo tori o yan Jesebeli ni aya...sugbon a ko k'ekòó nipa awon l'óko l'áyà yi l'oni bikoşe omiran bii ti won; Samsoni....d'arapo mo wa fun èkó ti oni👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻👨💻..... Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


To round up this series, it is important that we look briefly at a life of a man of God who fearlessly answered his 'yes alone' doing everything the Lord required of him as we read from 1 Kings 17:1-7, 8-11&15....Chapter 19 comes on later.....study with us....👨💻👩💻🧑💻🧑💻👩💻👨💻 Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Looti yan lai ni arojinle awon ipalara ti gbigbe iha ila-oorun pelu awon ti oju Olorun koro si; le e fa fun ohun ati idile re......tesiwaju eko yi pelu wa ni Genesisi ori kokan-din-l'ogun{19}......👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻....... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082


Listen to today's study episode friends and learn the important lesson that: God does not stop us from making choices apart from his will or outside his will; we just must be ready to face the consequences. Think about it.....🤔🤔...👩💻🧑💻👨💻👩💻👨💻🧑💻👩💻👨💻🧑💻👩💻👨💻.......


Kini a n pe ni àşàyan? Báwo ni ó ti le şe àkóbá fun ìwà àti ìşe bi eniti o n yan ko ba kíyèsára tabi l'arojinle? D'arapo mo wa l'ori eko onipele titun yi ka jo wa oro Olorun jinle....👩💻👨💻🧑💻👩💻👨💻🧑💻👩💻👨💻🧑💻👨💻 Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com (+44)7417522082


Genesis chapters 12&13 is where we'll be reading today as we look at what was meant to be a "yes alone" but took an extra company....."a relative".....against God's instructions....join us and let's study together 👨💻👩💻🧑💻👩💻🧑💻👨💻👨💻👩💻🧑💻 Contact us via email: reviewseries20@gmail.com (+44)7417522082


L'oni, ę ję ki awa naa ķó èkó pàtàkì ninu ohun ti Jesu fi ko awon omo ehin nipa isinmi l'ati inu iwe Marku 6.....d'arapò mó wa...👩💻🧑💻👨💻🧑💻👩💻👨💻👩💻🧑💻👨💻👨💻👩💻🧑💻...... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com +447417522082


Moses who earlier on complained about eloquence, standing to face Pharaoh, etc and wanted a company asides God had to stand alone to quickly bring the people back to God when Aaron decided to put the laws of God(Exodus 20:3&4) by the side, yielding to public pressure.....Exodus 32:1-6, 21-25......or read all...👨💻👩💻👨💻🧑💻👩💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻.... Contact Us via email: reviewseries20@gmail.com +447417522082


D'arapo mo wa l'ati wo ohun ti Olorun pa l'ase ni sise itoju ago ara wa l'ati le sin-in pelu otito inu ati okan ti o ye kooro.....👩💻🧑💻👩💻🧑💻👩💻🧑💻👩💻🧑💻....


Welcome again to another year where we shall continue to review the word of God to encourage, motivate and lift our spirits...why don't you start this brand new series with us,...and then continue to come back for more every weekend? Let's study the ancient word together...👨💻👩💻👨💻👩💻🧑💻🧑💻👩💻👨💻.....


D'arapo mo wa l'ati dupe fun aşeye Odun nigbati a o maa fi odun wa titun le Olorun l'owo pelu....E je ki a gbadura 🙏🙏🙏🙏🙏.....


Join us on review to give thanks unto the lord and praise him, also to commit the new year unto him....Amen....🎵🎶🔊🎼🥁🎻🎺💃🕺🥁🎹🎼....


D'arapo mo wa ka jo wo ohun ti o şęlę si Maria ati Josefu ni akoko akobi omo won tii şe omo Olorun....ani Jesu Kristi...Bawo ni keresi akoko ti ri??🤔...🎻🎺🎷🎼🎼🎶🎵👑👑👑🎹🎵🎶🥁🥁.... Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com 07417522082(+44)


Join our friends Stephen, Leah and Noah as they they present the last topic for the year(2023); inviting mum(Esther) as their 'guest'.....It's Christmas; What do you see? What have you always seen?🤔🤔.....🌲🌲🎶🎵🎼🎹🥁🎻🎺🎷🌲🌲👑👑👑👑... Contact us via email; reviewseries20@gmail.com


Matiu 1:18-25...d'arapo mo wa l'ati wo oba ti a bi fun igbala araye ti o si tun pe ara re ni: "Oluso aguntan rere"...Johannu 10:11.....👑🎷🎺🎶🎵🥁🎻🎹🎼🔊💃💃👑...... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com


What do you wanna be when you grow up?🤔...😊....why don't you join us to find out what this is all about as you start your Christmas here, celebrating the true and one kind of a king👑👑👑🎷🎺🎻🥁🎶🎵🎹🎼🔊🔊.... Contact us via email: reviewseries20@gmail.com